Cantiga Iemanjá
Cantiga Iemanjá
Cantiga Iemanjá
AGUERÉ
1. Iyá Ogun o
Iyemanjá
Iyá doje gbe
Iyemanjá
Iya mi oyo
Oyo l’ese
Omi an guere an guere we
Iya olokun
F’ara igi b’onã
K’emi f’ara erun aiye
IGUIDA
6. Iyemanja lese
Bi aro
Iya odo lese
Bi aro
A insaba ti lasa
Iyemanja lese
Bi aro
14. Mi mo fere
Mi m’anja r’ewá e
Eni iya l’ode
E mi mo fere
Mi m’anda r’ewá e
Eni iya l’ode
15. E oloiye e e
Fara lobi
Fara lobi wá
AGABÍ
21. Akoro se in si
Tani b’ojo
Tani b’oja re
Akoro se in si
Tani b’oja re
E Ogera orisá
Orisa osi oguera (orisa ki m’awa o) (oguera ori o)
ALUJÁ
25. Iyemanja un to
M’oja re
Iya (OLOJA, INTILÉ, IYA SESU...) ta mi m’oja re
ILÚ
29. To iza a e
To iza to iza e
To iza iya l’apa ogun
To iza
To iza e
NLÓ
(VAMUNHA)
36. Meta oyo f’ara aje do k’aiya
E un to
(MODUBÍ)
37. Aiyagba ke mi j’oba
Inmole
Ke mi j’oba awo