Eku Ifa
Eku Ifa
Eku Ifa
Eku réé o
A rat never make noise and that is why we should swallow his head
Eja réé o
Eja ni kó bani ja ofo, egba, oran ato gbogbo ajogun ibi kuro Ioruni ọmọ náá
The fish usually says that it is far from dying so the child must eat the fish
The fish says that it is disease-free so the disease must get away from the fish
This fish says that it is free of any kind of evil, that's why the evils must get away
Orogbo ree
Obi réé o
Obi níi be iku
Obi yóó be ikú fún ọmọ yií o
Obi níí be arun
Obi yóó be ikú fún ọmọ yíi o
Obi níi be ofo
Obi yóó be ikú fún ọmọ yíí o
Obi níi be ese
Obi yóó be ikú fún ọmọ yíí o
Obi níi be egba
Obi yóó be egba fún ọmọ yií o
Obí níi be ọmọ arayé aboju pete
Obi yóó e ọmọ arayé fún ọmọ yíí o
Oyin réé o
The world will not be able to get anything bitter in this child's life
Áádun réé o
May the life of this child always find sweetness on the part of people
Sugarcane
Iréké réé o
When people want sugar it is always taken care of until it finishes germinating
May enemies never cut down the life of this child like sugarcane
Atare
Atááre réé oo
Suga réé o
Imunmun réé o
Epa réé o
Iro réé o
Very cold is the river of the Oluweri and Oluweri’s domain is never hot
Oti réé o
Ogédé réé o