OC Ukeje
OC Ukeje | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Okechukwu Ukeje 15 Oṣù Keje 1981 Lagos State, Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | University of Lagos |
Iṣẹ́ | Film actor, model, musician |
Ìgbà iṣẹ́ | 2007— present |
Television | Amstel Malta Box Office realiyTV Show |
Olólùfẹ́ | Senami Ibukunoluwa Togonu-Bickersteth (m. 2014) |
Awards | 2008 Africa Movie Academy Awards for Most Promising Actor |
Okechukwu Ukeje /{{{1}}}/, tí àọn ènìyàn tún mọ̀ sí OC Ukeje jé òṣèrékùnrin ilẹ̀ Nàìjíríà,[1]àti olórin.[2] Ó di gbajúmọ̀ lẹ́yìn tó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Amstel Malta Box Office (AMBO).[3] Ó ti gba ọ̀pọlọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ bí i Africa Movie Academy Awards, Africa Magic Viewers Choice Awards, Nollywood Movies Awards, Best of Nollywood Awards, Nigeria Entertainment Awards àti Golden Icons Academy Movie Awards. Ó sì ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù àgbéléwò lóríṣịríṣi tó ti gba ọ̀pọ̀ àmì-ẹ̀yẹ, bí i Two Brides and a Baby, Hoodrush, Alan Poza, Confusion Na Wa àti Half of a Yellow Sun.[4]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Okechukwu Ukeje wá láti ìlú Umuahia,[5] ní Ipinle Abia, àmọ́ Ìpínlẹ̀ Èkó ní Nàìjíríà ni wọ́n bi sí tó sì dàgbà sí. Òun ni ọmọ kejì láàárín àwọn ọmọ mẹ́ta ti òbí rẹ̀ bí.[6]
Iṣẹ́ tó yàn láàyò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ilé-ìwé Federal Government College Ijanikin, ní Ojo, ní Eko ni ó lọ. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré-ṣíṣe nígbà tó wà ní ọdún kìíní ní University of Lagos, Yaba, pẹ̀lú eré orí-ìtàgé kan. Ó tẹ̀síwájú láti ṣe iṣẹ́ orin kíkọ àti eré-ṣíṣe, àmọ́ eré orí-ìtàgé ló fi bẹ̀rẹ̀, ó sì ṣe é fún ọdún mẹ́rin àkọ́kọ́ kí ó tó gba àmì-ẹ̀yẹ ti ètò Amstel Malta Box Office (AMBO).[7] Ìfarahàn àkọ́kọ́ rẹ̀ lórí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán wáyé nínú fíìmù White Waters (2007) pẹ̀lú Joke Silva àti Rita Dominic. Izu Ojukwu sì ni olùarí erẹ́ náá. Ó gba àmì-ẹ̀yẹ Africa Movie Academy Awards (AMAA) fún òṣèrékùnrin tó dára jù lọ ní ọdún 2008, àti City People's Award fún Best New Act (2010).[8]
Kò dẹ́kun orin kíkọ. Ó ṣịṣẹ́ pẹ̀lú àwọn olórin mìíràn ní Nàìjíríà. Ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀ fíìmù àti ètò orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán láàárín ọdún 2008 àti 2012.[9]
Ìgbésí ayé ara ẹni
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ukeje ń gbé ní Eko, ní Nàìjíríà. Arábìnrin Senami Ibukunoluwa Togonu-Bickersteth ni ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú ní 8 November 2014.[10][11]
Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Fíìmù | Ojúṣe | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|
2007 | White Waters | Actor | |
2008 | Comrade | Hakeem | |
2011 | Black Gold | Peter Gadibia | |
Two Brides and a Baby | Badmus | ||
2012 | Black November | Peter Gadibia | |
Hoodrush | Shez Jabari | ||
Till Death Do Us Part (Short) | John | ||
2013 | Confusion Na Wa | Charles Duka | |
Alan Poza | Alan Poza | ||
Half of a Yellow Sun | Aniekwena | ||
Awakening | Nicholas | ||
Gone Too Far | Iku | ||
The Rubicon | David | ||
2014 | When Love Happens | Dare | |
Gidi Up (TV Series) | Obi (2014 – ) | ||
A Play Called a Temple Made of Clay (Short) | Hakeem | [12] | |
2015 | The Department | Segun | |
Before 30 | Ayo (2015-) | ||
2016 | The Arbitration | Mr. Gbenga | |
Remember me | |||
North East | Emeka Okafor | ||
2017 | Potato Potahto | Mr. Tony Wilson | [13][14] |
Catch.er | Detective Komolafe | ||
2018 | Shades of Attraction | ||
In Sickness and Health | |||
The Royal Hibiscus Hotel | |||
2019 | Heaven's Hell | Ahmed | |
Ashen | |||
2020 | Shine Your Eye | Amadi | |
2022 | Black mail | [15] | |
2022 | Brotherhood | Izra | |
2023 | Orah | Agent Uche Odi |
Àmì-ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Fíìmù | Èsì | Ìtọ́ka |
---|---|---|---|---|---|
2008 | Africa Movie Academy Awards | Most Promising Actor | White Waters | Gbàá | |
2012 | Africa Movie Academy Awards | Best Actor in a Leading Role | Confusion Na Wa | Wọ́n pèé | |
2013 | Nigeria Entertainment Awards | Best Lead Actor in a Film | Alan Poza | Gbàá | |
Best of Nollywood Awards | Best Lead Actor in an English Movie | Gbàá | |||
Nollywood Movies Awards | Best Actor in a Lead Role | Hoodrush | Gbàá | [16] | |
Africa Magic Viewers Choice Awards | Best Actor in a Drama | Two Brides and a Baby | Gbàá | [17] | |
2019 | Best of Nollywood Awards | Best Actor in a Lead role – English | Unbreakable | Wọ́n pèé | [18] |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Adebayo, Tireni (2021-07-16). "OC Ukeje quietly marks 40th birthday". Kemi Filani News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-12.
- ↑ I’m Attracted To Older Women – Okechukwu Chukwudi Ukeje 6 November 2012
- ↑ "OC Ukeje, Actor". Mandy. Retrieved 2016-05-13.
- ↑ "List of winners of Nigeria Entertainment Awards 2013".
- ↑ "Why women send nude photographs to me - OC Ukeje". naijanewsmagazine.blogspot.com. 10 June 2013.
- ↑ "Nigeria: OC Ukeje, Majid Breaking the Cinemas". allAfrica.com. Retrieved 2016-05-13.
- ↑ "How I handle my female admirers —O.C Ukeje". Vanguard. http://www.vanguardngr.com/2011/05/how-i-handle-my-female-admirers-%E2%80%94o-c-ukeje/.
- ↑ Systems, Clearwox. "Oc Ukeje on iBAKATV | Home for Nollywood Movies". ibakatv.com. Archived from the original on 2016-08-22. Retrieved 2016-05-13.
- ↑ "O.C. Ukeje". IMDb. Retrieved 2016-05-13.
- ↑ "OC Ukeje Shares On His Marriage Experience And How He Met His Wife". Pulse Nigeria TV. Misimola. 19 May 2015. Archived from the original on 4 March 2016. Retrieved 19 May 2015.
- ↑ "Nollywood actor, OC Ukeje weds at 33 – Nigerian Entertainment Today – Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games" (in en-GB). Nigerian Entertainment Today – Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games. 2014-11-10. http://thenet.ng/2014/11/nollywood-actor-oc-ukeje-weds-at-33/.
- ↑ 'Kusare, Mak (2000-01-01), A Play Called a Temple Made of Clay, retrieved 2016-05-13
- ↑ "Shirley Frimpong-Manso's 'Potato Potahto' makes it to Netflix - MyJoyOnline.com". www.myjoyonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-02-03.
- ↑ Frimpong-Manso, Shirley (2019-12-15), Potato Potahto (Comedy), O. C. Ukeje, Joselyn Dumas, Joke Silva, Kemi Lala Akindoju, 19 April Entertainment, Ascend Studios, Lufodo Productions, retrieved 2021-02-03
- ↑ "Obi Emelonye's 'Black Mail' Opens in 100 UK Cinemas – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-08-04.
- ↑ "Phone Swap, OC Ukeje and Rita Dominic Win Big at 2013 NMA". Channels Television. Retrieved 2022-07-22.
- ↑ Inyang, Ifreke (2013-03-10). "Mercy Johnson, Mirror Boy, Jackie Appiah, OC Ukeje - See full list of winners from AMVCA 2013". Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-22.
- ↑ Bada, Gbenga (2019-12-15). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-10.