Lára e ko-ilé tí a máa ń fún ọmọ ní ile Yorùbá ni bí a ṣe ń lo èdè tàbí so ro ní àwùjọ pe lú àwọn ìṣe àti ìhùwàsí Yorùbá tó sodo sínú àṣà wọn. Èyí ló máa ń mú kí wo n bá àwùjọ mu, kí ètò sì wà láàrin ìlú. Àmo ṣá, ìrírí wa lóde-òní ni pé o...
moreLára e ko-ilé tí a máa ń fún ọmọ ní ile Yorùbá ni bí a ṣe ń lo èdè tàbí so ro ní àwùjọ pe lú àwọn ìṣe àti ìhùwàsí Yorùbá tó sodo sínú àṣà wọn. Èyí ló máa ń mú kí wo n bá àwùjọ mu, kí ètò sì wà láàrin ìlú. Àmo ṣá, ìrírí wa lóde-òní ni pé o po ilé ló ti sọ èdè àti àṣà Yorùbá nù. Èyí sì ti pagidínà ètò àti ìwà ọmọlúàbí ní àwùjọ. Láti gbé èdè àti àṣà Yorùbá lárugẹ, o po ilé-iṣe rédíò aládàáni ni àwọn olùfe èdè àti àṣà Yorùbá ti dá síle. O kan gbògíì sì ni ilé-iṣe rédíò Lágelú ní Ìbàdàn je nínú wọn. Látàrí èyí, iṣe yìí wádìí ìwòye àwọn olùgbo nípa ipa tí ètò Yorùbá lórí rédíò Lágelú ń kó nínú kíko ará ìlú ní èdè àti àṣà Yorùbá, nípa gígùnlé tío rì Ìfàkíyèsínímo àti tío rì Ìgbo kànlé. Ìfo ro wánile nuwò ni a ṣe fún àwọn olùgbo me fà àti ato kùn ètò Yorùbá me ta tí a mo o nmo yàn fún iṣe yìí. A tún fetí sí àwọn ètò me te e ta náà (Oríkì Ile Wa, Láwùjọ Àgbà àti Tiwa N Tiwa) ní àìmọye ìgbà kí á lè ṣe àfiwé ìwòye àwọn olùgbo àti