Mi MOYUMBA AL SANTO
Mi MOYUMBA AL SANTO
Mi MOYUMBA AL SANTO
Ori bawa olorun, ori bawa olofin, ori bawa lode, inle kun inchele unfe edun inle oguere
aboboniche olodumare modupue olorun.
Otun ni oba, osin ni alawo ache, gere gere lery omaya. Omi tuto, ona tuto, tuto inle, tuto
owo, tuto larogba, tuto la ferola, tuto lawe ykoko ariku babawa.
Igba inle afokan, igba inle oguere, igba eyite, igba irawo, igba chupua, igba orumila, igba
bogbo orumole gicoyun, igba bogbo irumole gicosin, IGBA BOGBO EGUN igba olorun
akokoibre.
Olorun titiloke eruwa aye ki olofin eruwa aye mofoyugba olorun,omi omi ofi eggun, omi
omi ofi inle, omi omi ofi olorun agbaji olodumare,ogunda tetura ifa omi igba unlo ni timoen
un ayentonu timbe elese olodumare.
Bogbo awo tokun, bogbo iya locha tokum, to lawa lawa tokum, bogbo eggun ni ko inle, bogbo
eggun ara, bogbo eggun chebo, bogbo eggun ore, bogbo eggun chebo ni ofun sa, bogbo
eggun chebo ni oluwo sigayu ,bogbo eggun chebo ni yubon, bogbo eggun chebo ni apeterbi ,
bogbo eggun chebo ni iyalocha , bogbo eggun chebo ni yubona ka de kariosha , bogbo eggun
chebo ni omokenkeres, bogbo eggun chebo ni: fulano de tal.
ASHE OLOFIN,
ASHE OLODUMARE,
ASHE ODUDUWA
, ASHE BOGBO EGUN ARA ONU KE TIMBELESE OLODUMARE,
ASHE MI ANGEL DE LA GUARDA SHANGO, SHANGO Alaafin, ekun bu, a sa Eleyinju
ogunna Olukoso lalu A ri igba ota, según Eyi ti o fi alapa segun ota re Kabiyesi o Ase