Decolonise the Internet (Nigeria/Yorùbá Wikipedia)
Bí ó ṣe bẹ̀ré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]àjọ jẹ́ àjọ kan tí ó ń mojú tó àṣà abínibí kan ní orílẹ̀-èdè agbáyé tí ó fìdí kalẹ̀ sí orílẹ̀-èdè Germany. Wọ́n ma ń gbé àṣà àti ìṣe orílẹ̀-èdè Germany lárugẹ jákè-jádò àgbáyé tí wọ́n sì ma ń tún ṣe alábàápín àṣà àti ibikíbi tí wọ́n bá ti dé láyé.
Àjọ Wikimedia User Group Nigeria (WUGN) náà jẹ́ ọ̀kan lára àwọn orísiríṣi ẹ̀ka Wikimedia Foundation Inc, tí ó kalẹ̀ sí agbègbè San Fransisco ní orílẹ̀-èdè USA tí ó jẹ́ àjọ tí kò dúró láti máa pawó sápò tí kìí sì ń ṣe ti ìjọba tí ó jẹ́ alákòóso gbogbo gbò fún àwọn ẹ̀ka wọn lágbàáyé ni wọ́n yọ̀nda fún ajọ Wikimedia Nigeria User Group lábẹ́ àkóso àṣẹ iṣẹ́ ọ̀fẹ́ wọn láti máa bá wọn polongo àwọn iṣẹ́ àkànṣe wọn gbogbo ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Iṣẹ́ àkànṣe Decolonise the Internet
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹ̀Rọ ayélujára ni a rí gẹ́gẹ́ bí ohin èlò pàtàkì lásìkò yí, pàá pàá jùlọ ioa tí ó ń kó nínú ètò ìṣèlú àti ìṣe déédé láwùjọ wa gbogbo. Ní àsìkò àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 ní orílẹ̀ àgbáyé gbogbo, ẹ̀rọ ayélujára ni ó so wá pọ̀ tí ó sì fi ìfẹ́ wa síra wa rinlẹ̀ ṣi ṣin inú ọdún 2020. Ó yẹ kí á bèrè lọ́wọ́ ara wa ọ̀nà tí àwọn Artificial Intelligence, Algorithm àti àwọn bọ́ọ̀tì ṣe yí ìwòye wa padà nípa bí ayé ṣe ń lọ sí láì fi tẹ̀yà kankan ṣe. Èyí ni ó fàá ti àjọ Goethe ṣe gbé iṣẹ́ àkànṣe "Decolonise the Internet" kalẹ̀.
Ìdíje Decolonise the Internet
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìdíje "Decolonise the internet" jẹ́ ìdíje kan tí a vbé kalẹ̀ láti fi bu ọlá fún awọn obìnrin tó fakọyọ jùlọ ní orílẹ̀-èdè àgbáyé pàá páà jùlọ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a wà yí láì fi ti ẹ̀yà òun ẹ̀sìn ṣe. Bá kan náà ni a ń wá ẹni tí ó lè ṣe akọsílẹ̀ àwọn akòrí tuntun sí orí ìkanì Wikipedia.
The contest will focus on four Wikipedia projects namely: Ìdíje náà yóò dá lórí àwọn èdè mẹ́rin tí ó wà ní orílẹ̀-èdè.Nàìjíríà. Àwọn.ni:_
Ìdíje náà yóò.wáyé láàrín 2nd sí 5th November 2020.
Àtòjọ Àwọn Àkòrí àwọn Obìnrin náà nìyí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Dupsy Abiola
- Bilikis Adebiyi Abiola
- Ronke Ademiluyi
- Ọlájùmọ̀kẹ́ Adénọ́wọ̀
- Jackie Àìná
- Chief Tèmítọ́pẹ́ Àjàyí
- Nike Àkàndé
- Toyosi Akerele Ogunsiji
- Omoyemi Akerele
- Omowumi Akinifemisi
- Adenike Akinsemolu
- Folorunso Alakija
- Bolanle Austen-Peters
- Hannah Idowu Dideolu Awolowo
- Ibukun Oluwa Abiodun Awosika
- Quincy Olasumbo Ayodele
- Bunmi Banjo
- Banke Meshinda-Lawal
- Aduni Bankole
- Ola Brown
- Funke Bucknor-Obruthe
- Fola Coker
- Florence Ifeoluwa Otedola
- Shola David-Borha
- Bella Disu
- Temie Giwa-Tubosun
- Ade Hassan
- Amy Jadesimi
- Kehinde Kamson
- Alaba Lawson
- Ore Oluwalesi
- Lola Maja
- Abibatu Mogaji
- Tóún Òkèwálé Ṣónáìyà
- Ṣadé Ọkọ́ya
- Fúnkẹ́ Òpéke
- Tósìn Ọsìnọ́wò
- Fúnkẹ́ Òṣíbódù
- Roseline Òṣípìtàn
- Àlímọ́tù Péléwúrà
- Sahsa P
- Bọ́lá Ṣàgàyá
- Jọkẹ́ Silva
- Tẹ́ní
- Uduak Isong
- Ẹniọlá Badmus
- Adétóun Ògúnṣẹ̀yẹ
- Dúpẹ́ Olúṣọlá
- Témì Balógun
- Elizerbeth Abímbọ́lá Awoliyi
- Aríọlá Ọlásùnbọ̀ Sànyà
- Yétúndé Phillps
- Folashade Sherifat Jaji
- Folake Solanke
- Funmi Tejuosho
- Suzanne Iroche
- Lateefat Okunnu
- Titi Oyinsan
- Tonye Garrick
- Lara George
- Fifi Ejindu
- Olaoluwa Abagun
- Kemi Lala Akindoju
- Grace Alele-Williams
- josephine Anenih
- Oluwafunmilayo Olajumoke Atilade
- Ndid Nnoli-Edozien
- Olajumoke Adenowo
- Halima Tayo Alao
- Omotade Alalade
- Titilope Gbemisola Akosa
- Adetola Juyitan
- Ruka Sanusi
- Oby Ezekwesili
- Hauwa Ibrahim
- Ayesha Imam
- Mariama Keïta
- Ndid Nnoli-Edozien
- Jennifa Uchendu
- Nkiru Balonwu
- Jadesola Akande
- Aramide Sarumoh
- Olufunke Adeboye
- Adeola Olubamiji
- Deborah Ajakayie
- Mojisola Adeye
- Funke Abimbola
- Adeyinka Gladys Falusi
- Adenike Grange
- Simi Johnson
- Oluwatoyin Asojo
- Tejumade Alakija
- Sara Alade
- Ayo Ayoola-Amale
- Adejoke Ayoola
- Grace Ebun Delano
- Títílọlá Òbílàdé
- Jùmọ̀kẹ́ Odùwọlé
- Kate Okikiolu
- Margaret Ọládípọ̀
- Péjú Láyíwọlá
- Oluwayemisi Oluremi Obilade
- Ọmọ́wùmí Sadik
- Oyèrónkẹ́ Oyèwùmí
- Sophie Olúwọlé
- Yéwandé Olúbùmọ́
- Fúmi Ọlọ́níṣakin
- Grace Oladuni Taylor
- Ọláìtán Ṣóyanńwò
- Lindsey Abudei
- Ada Ehi
- Afro Candy
- Bella Alubo
- Amarachi
- Asikey
- Mercy Chinwo
- Nikki Laoye
- Demi Grace
- Maheeda
- Niniola
- Emma Nyra
- Sunkanmi Rehanat Alonge
- Temmie Ovwasa
- Yewande Omotoso
- Hafsat Abiola
- Smaranda Olarinde
- Iheoma Obibi
- Saudatu Mahdi
- Hadiza Bala Usman
- Oyinkansola Ayobami
- Nwando Achebe
- Cathrine Obianuju Acholonu
- Bisi Adeleye Fayemi
- Sandra Aguebor
- Judith Amaechi
- Nana Asma'u
- Joy Isi Bewaji
- Molara Ogundipe
- Julie Okoh
- Ayodele Olofintuade
- Chioma Opara
- Florence Ozor
- Yemisi Ransome Kuti
- Adanna Steinacker
- Bilikisu Yusuf
- Folashade Abugan
- Kemi Adekoya
- Aminat Adeniyi
- Sekinat Adesanya
- Florence Ajayi
- Airat Bakare
- Lola Akinmade Akerstrom
- Ebun Oyagbola
- Aduke Alakija
- Yewande Akinola
- Grace Oyelude
- Aderonke Kale
- Agness yewande Savage
- Remi Vaughan-Richard
- Ronke Odusanya
- Jumoke Odetola
- Kofoworola Ademola
- Dayo Amusa
- Abimbola Alao
- Uduak Archibong
- Sarah Jibril
- Leila Fowler
- Christie Ade Ajayi
- Abisoye Ajayi-Akinfolarin
- Uju Ohanenye
- Aishat Abubakar
- Olawunmi Banjo
- Sonya Clark
- Amina J. Mohammed- ígbákejì alaga fún Igbimọ gbogboogbo ti orilẹ-ede Agbaye
- Bilkisu Labaran
- Obianuju Ekeocha
- Iroro Tanshi
- Adeyinka Gladys Falusi
- Uko nkole