Diana Ross
Ìrísí
Diana Ross | |
---|---|
Diana Ross performing at the 2008 Nobel Peace Prize concert in Oslo | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Diana Ernestine Earle Ross |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kẹta 1944 |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Detroit, Michigan, U.S. |
Irú orin | R&B, soul, disco, jazz, pop, dance |
Occupation(s) | Singer, record producer, actress |
Years active | 1959–present |
Labels | Lu Pine, Motown, RCA, EMI |
Associated acts | The Supremes, The Temptations, The Jackson 5, Marvin Gaye, Michael Jackson, Lionel Richie |
Website | www.dianaross.com |
Diana Ernestine Earle Ross (born March 26, 1944[1]) je olorin ati osere ara Amerika. Ross loje olorin asiwaju fun egbe akorin The Supremes ni Motown nigba ewadun 1960. Leyin to fi egbe yi sile ni 1970, Ross bere si ni dakorin be sini o bere si ni se filmu ati ere ni Broadway. O gba idaloruko fun Ebun Akademi bi Osere Obinrin Didarajulo fun ipo ere re bi Billie Holiday ninu filmu Lady Sings the Blues (1972), eyi to gba ebun Wura Olobirikiti fun. O gba opo awon Ebun Orin ara Amerika, idaloruko garnered twelve Ebun Grammy mejila, ati o si gba Ebun Tony fun ere ori-itage re to n je, An Evening with Diana Ross, ni 1977.[2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2012-05-04. Retrieved 2011-10-11.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2012-03-15. Retrieved 2011-10-11.