Jump to content

Edmund Husserl

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Edmund Husserl
Edmund Husserl in about 1900.
OrúkọEdmund Husserl
ÌbíApril 8, 1859
Proßnitz, Moravia, Austria (present-day Prostějov, Czech Republic)
AláìsíApril 28, 1938(1938-04-28) (ọmọ ọdún 79)
Freiburg, Germany
Ìgbà20th-century philosophy
AgbègbèWestern Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Phenomenology
Ìjẹlógún ganganEpistemology, Ontology, Mathematics
Àròwá pàtàkìPhenomenology, epoché, natural standpoint, noema, noesis, eidetic reduction, phenomenological reduction, retention and protention, Lebenswelt, pre-reflective self-consciousness[1]

Edmund Gustav Albrecht Husserl (Jẹ́mánì: [ˈhʊsɐl]; April 8, 1859 – April 26, 1938) je amoye ati onimo mathimatiki ati oludasile eko imoye igba odunrun 20k to n je fenomenoloji. O pinya kuro lati idojude asedidaju oro sayensi ati imoye to gbajumo nigba aye re, sibesibe o se ekunrere irolebi iserirotan ati isetorookan ninu ogbon.


  1. Shaun Gallagher and Dan Zahavi's term for Husserl's idea that consciousness always involves a self-appearance (für-sich-selbst-erscheinens); "Phenomenological Approaches to Self-Consciousness", Stanford Encyclopedia of Philosophy.