Jump to content

Godwin Obaseki

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Godwin Obaseki
Obaseki ni ọdún 2018
Gómìnà ìkẹwà tí ìpínlẹ̀ Edo
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Ọ́jọ́ ìkejìla Bèlu, 2016
DeputyPhilip Shaibu
AsíwájúAdams Oshiomhole
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Godwin Nogheghase Obaseki

Àdàkọ:Ọjọ́ ìbí àti ọjó orí
Ìlú Benin, Ìpínlẹ̀ Edo, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNàìjíríànù
Ẹgbẹ́ olóṣèlú People's Democratic Party (PDP)
(Àwọn) olólùfẹ́Betsy Bene Obaseki
Àwọn òbíOgbeni Roland Obaseki
Stella Osarhiere Gbinigie
Alma materEghosa Grammar School ní Ìlú Benin
University of Ibadan
Columbia University
Pace University
Websitegodwinobaseki.com

Godwin Nogheghase Obaseki (Ọjọ́ ìbí: 1 Agẹmọ, 1957, ní Ilu Benin, Nigeria [1] ) jẹ́ olóṣèlú àti oníṣòwò kan ní ìlú Naijiria to sì jẹ Gómìnà Ipinle Edo àtọwò. Wọ́n gbé ìpò gómíná fun ní ọjó ìkejìla, Bèlu, 2016 ní. Oun lo jẹ́ Olóyè Edo State Economic and Strategy Team látọwọ́ gómìnà ìṣáájú, Adams Oshiomole, ní òṣù Erẹ́nà, l ọdún 2009.

  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-12-26. Retrieved 2019-12-13.