Ram Narayan
Ìrísí
Ram Narayan | |
---|---|
Narayan in Delhi in October 2010 | |
Background information | |
Irú orin | Hindustani classical music |
Instruments | sarangi |
Years active | 1944–2013 |
Associated acts | Abdul Wahid Khan, Brij Narayan, Chatur Lal, Suresh Talwalkar |
Website | ramnarayansarangi.com |
Ram Narayan (Híndì: राम नारायण; IAST: Rām Nārāyaṇ, IPA: [ˈraːm naːˈraːjn]; 25 December 1927 -9 November 2024), nigba miran ti won unpe ni Pandit, je olorin ara India to mu irinse orin sarangi gbajumo bi irinse orin agbo adalu ninu orin ogbologbo Hindu to si gbajumo kariaye bi onilu sarangi.
Narayan je bibi ni Udaipur o si ko lati ta sarangi lati igba kekere.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |