Jump to content

Marseille

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gbọ̀ngàn Ìlú Marseille

Marseille (ìpè Faransé: ​[maʁ.ˈsεj]) jẹ́ ìlú èbúté ìgbàanì, èyí tá a dá nǹkan bíi 600 ṣááju Sànmánì Tiwa, ní apá gúúsù-ìlàoòrùn Fránsì. Agbègbè náà tóbi tó 240.62 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 858,120 nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]