Jump to content

Susan Rice

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Susan Rice
27th United States Ambassador to the United Nations
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
January 22, 2009
ÀàrẹBarack Obama
AsíwájúZalmay Khalilzad
12th Assistant Secretary of State for African Affairs
In office
October 9, 1997 – January 20, 2001
ÀàrẹBill Clinton
AsíwájúGeorge Moose
Arọ́pòWalter Kansteiner
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Susan Elizabeth Rice

17 Oṣù Kọkànlá 1964 (1964-11-17) (ọmọ ọdún 60)
Washington, D.C., U.S.
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic Party
(Àwọn) olólùfẹ́Ian Cameron (1992–present)
Àwọn ọmọ2
Alma materStanford University
New College, Oxford
Susan E. Rice (middle) at the USCIRF hearings (November 27, 2001).

Susan Elizabeth Rice (ojoibi November 17, 1964) je diplomati ara Amerika, elegbe think-tank tele, ati lowolowo Asoju Orile-ede Amerika ni Agbajo Asokan awon Orile-ede. Rice ti sise tele ni Igbimo Abo Onitomoorile-ede ati Oluranwo Alakoso Oro Okere fun Afrika ni asiko igba keji Aare Bill Clinton. Rice je pipe ni Asoju si Asokan awon Orile-ede pelu ifenuko alainitako ni Ile Alagba Amerika ni January 22, 2009.