SECOND TERM SS 3 YORUBA
SECOND TERM SS 3 YORUBA
SECOND TERM SS 3 YORUBA
YORUBA LANGUAGE
OSE AKORI EKO
3 EDE – Atunyewo eko lori oro ayalo minu oro ayalo wo inu ede
Yoruba
ASA – Atunyewo kikun lori ede eto iselu abinibi ati ode-oni
5 EDE – Atunyewo eko lori isori oro; oro oruko, oro aropo
oruko, aoro aropo afarajoruko, oro ise
ASA – Atunyewo eko lori oge sise, aso wiwo, itoju ara, ila kiko
abbl.
6 EDE – Atunyewo eko lori isori ori apejuwe, oro aponle, oro
asopo ati oro atokun
OSE KI IN NI
AKORI EKO: EGBE AWO LORISIRISI
Ohun to soro lati mo kulekule ohun ninu egbe awo nitori won kofi eni ti kii se omo egbe idi
niyi ti o fi je omo egbe lo le so pelu idaniloju ohun ti o n sele ninu egbe won.
Pataki ise opolopo awon egbe awo wonyi ni fun idagbasoke ati alaafia ilu ti okan si n gbe
ekeji ni igbonwo. Bi apeere, egbe oro wa fun sise abo ati eto ti o ye lori ipinnu ti o bati odo
egbe ogboni wa nipa eto ilu.
Tajateran ko nii se egbe ogboni, kaka bee o wa fun awon agba to ni ojo lori. Ko si fun odo
obinrin afi awon ti o ti darugbo patapata ti Atari won to gbe eru awo. Bi apeere, Erelu okun.
If ti o yii ni oso awon omo egba poi di niyi ti won fi n pe ara won ni omo iya.
Awon omo egbe ni ani ti won fi n la ara won mo lawujo. Ami egbe pataki ni edan. Ako edan
wa fun nnkan ti ko ni ayo ninu ti abo si wa fun nkan ayo ati idunu.
Ninu leta aigbagbefe, ko si aaye fun iroyin tabi efe rara. Apeere irufe leta yii ni n ko si Ajete,
Olotuu iwe iroyin, Giwa ile-ise, Oba, Alaga igbimo, Alaga ijoba ibile, oga ile – iwe ati akowe
agba ibi ise ijoba apapo bii oga agba ajo idanwi WAEC, NECO ati JAMB.
b. Ikini Ibeere: Apa osi ni ila ta tele adiresi agbaleta ni akoleta yoo ko ikini akoko si leta n la ni
o gbodo fi bere yoo si fi ami koma kadii re. Apeere:
Olotuu,
Oga ile – iwe,
Akowe agba, abbl
d. Akole leta aigbefe: Ila ti o tele ila ikini ni akoleta yoo ko akole leta re si ni aarin iwe yoo si
fara sidii re ti o ba ti leta kekere ko o tabi ki o ko o nil eta nla lai fala si nidii. Apeere:
Ayeye Ojo Omiran Orile – Ede Naijiria.
e. Ara leta: Aaye ko si fun iforo jewoo tabi awada ninu leta yii, ohun ti a ba fe so ni pato ni a
gbodo gbe kale. Ti o ba si je esi iwe ti akoleta ko gba tele tabi ko ni a gbodo fihan.
e. Ikadii/ipari: owo otun ni isale iwe ni akoleta yoo ko igunle leta re si, oruko meji (iyen ni
oruko akoleta ati obi re) ni o gbodo ko pelu ami idanuduro ni ipari. Apeere:
Emi ni,
Biodun Agbabiaka.
(signature)
OSE KEJI
AKORI EKO: AWON ISERUN ENI (AWON BABA NLA ENI)
Nigbakuugba ti a ba menuba awon iserun eni awon eni igbaani to se awon eniyan kan sile ni
a n tokasi. Bi a ba si menubaawon iserun, awon to ti ku ni a n tokasi pelu kii se alaaye. Bi
baba ati iya to bi ni ba ku, iserun eni ni awon mejeeji, bi o ba si je pe baba ati iya to bi awon
obi wa naa ba si ti ku iserun eni ni awon naa. Bee ni a le maa tan an titi de ori eni to te agbo
ile tabi eni to se idile tabi iran kan sile. Iserun eni ni eni to se orile iran eni sile nigba laelae.
Oju orori loori se pataki ni ile Yoruba. Oju oori ni ibi ti a sin oku si. Igbagbo Yoruba ni pe
gbogbo igba ti a ba pe oku ni oju oori re, yoo dahun yoo si se ohun ti a ba fe.
Idi ti a fi gbagbo ninu awon iserun eni:
a. Ija pipari ni oju oori
b. Iranlowo jade kuro ninu isoro (B.A ti aje ba ri foro emi eni ti won si fe run agbo ile).
Airomobi, abiku.
d. Lati tu won loju (bibe won ki won wa ya si odo won)
OSE KERIN
ORO AYALO
Oro ayalo ni oro ti a ya lo lati inu ede kan wonu ede Yoruba tabi ede miiran ni ona ti pipe ati
kiko re yoo fi wan i ibamu pelu batani iro ede ti a ya a wo. A n ya oro lati sapejuwe asa
tuntun ti a n ba pade nipase owo sise, eto oselu, imo ero, imo sayensi, esin, eto amuluudun
laarin awon ti won n so ede kan ati elde miiran. Ni Pataki oro ayalo maa n je ki ede kun si,
ede ti ko bas i iyipada ninu re kii dagba.
1. Ajosepo ojo pipe ti wa laarin ijoba ile Geesi ati ile Naijiria: ati pe
2. Ede Geesi lo tun je ede ibara-eni-soro ni ile ise nibi apejo ati ni ile iwe
Orisii ona ti a le gba ya oro lati inu ede kan wonu ede Yoruba ni:
a. Ilana Afetiya: eyi ni ki atele liana bi a se fi eti gbo bi oro ti dun tabi bi awon elede se n pe
e. Bi apeere:
Tailor – Telo
Bible – Baibu
Peter – Pita
b. Ilana Afojuya – oro ayalo afojuya ni awon oro ti a ya nipa tilele liana bi awon elede ti a ya
won se n ko awon oro bee sile. Apeere
Table – Tabili
Milk – Milliki
Bible – Bibeli
Esther – Esiteri
Peter – Peteru
Ise asetilewa
1. School
2. Contractor
3. Plug
4. Driver
5. Starch
6. Train
7. Class
8. Brush
9. Fali
10. Film